O sele Gani Adams joye ninu ijo kerubu - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

ILEYA TI DE

ILEYA TI DE
ILEYA TI DE

Sunday, December 20, 2020

O sele Gani Adams joye ninu ijo kerubu

Aare ona kakanfo Ile Yoruba niroyin to te wa leti so pe awon Wolii kan ninu ijo Kerubu ti fi joye Aposteli ninu ijo won to wa ni Ikeja, ijo Saviour Ministry worldwide (C$S) lo foye Aposteli da Aare ona kakanfo iyen oloye Gani Adams l'ola.


No comments:

Post a Comment

Pages