- TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

ILEYA TI DE

ILEYA TI DE
ILEYA TI DE

Wednesday, April 14, 2021

Gbogbo ojo kerinla osu kerin ni ojo ibi gbajumo sorosoro Ori redio nni eniti gbogbo eeyan mo si Yeye Abidemi Olukuewu,ti omo Bibi ipinle Ogun naa si n fi emi imoore han si Eleda re,eto adura waye ni Ile re to wa nipinle Eko nibi ti awon sorosoro egbe re bii Aare Abiodun Adeoye Afefe Oro ati Alaaji Yekini Oyinlomo JoJo ti ba Yeye dupe lowo Olorun.Yeye Abidemi to tun je oludari ileese kan ti won ti n se kiriimu amaradan ti won so tun n ta awon aso ati irun igbalode tun was n dupe lowo awon ololufe e ti won ti fi ife gan si i fun ti ayeye ojo ibi re naa


No comments:

Post a Comment

Pages