Atorise olorin emi fi aidunnu re han lori ipo ti Orile ede Naijiria wa - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

ILEYA TI DE

ILEYA TI DE
ILEYA TI DE

Saturday, May 8, 2021

Atorise olorin emi fi aidunnu re han lori ipo ti Orile ede Naijiria wa

Okan ninu awon olorin emi ti ko se e fi owo to seyin kaakiri Orile ede yii ni Lanre Teriba eniti awon ti e mo si Atorise,ti omo Bibi ipinle Ogun naa si ti fi ehonu re han lori ipo ti Orile ede yii wa bayii.Atorise so pe se o digba to ba di Ogun ki Orile ede yii to dara ni?o tun so pe awa olugbe Orile ede yii gan an ni isoro ara wa,o je ko di mimo pe ominira ti a gba ti fa Ogun sinu aye awon olugbe Orile ede yii.
Atorise wa n gbadura pe Ogun ki yoo sele si wa lorile-ede yii,sugbon o wa n be awon Olori wa lati ranti awon mekunnu.Sa o Atorise ti so pe awon Olori wa lo n se wa lati aye ijoba alagbada to si n be won lati wa ojutu si isoro Orile ede yii nitori pe lati 1960 ti a ti gba ominira ni inira ti de ba awon olugbe Orile ede Naijiria.


No comments:

Post a Comment

Pages