
Owo ti te Ogbeni Isaac to je maneja Ile itura Kolab ni Itele Ota nipinle Ogun,Ogbeni naa to je omo odun metalelogbon ni owo iko Olopaa ipinle Ogun te leyin ti asiri tu pe ise asewo ni won n ko awon odobinrin to wa laarin odun mewa si mejila se.Oga Olopaa ipinle Ogun iyen Ogbeni Edward Awolowo fidi isele naa mule,ti o si to pase pe ki awon ti owo te naa wa lahamo Olopaa to wa nilu Sango.


No comments:
Post a Comment