
Ojo jimo to koja ni awon agbaagba oniroyin sepade ni Agbegbe ikeja nilu Eko,Ogbeni Aremu Adeniyi lo gba gbogbo awon oniroyin bii Ogbeni Joshua Uloko,Ogbeni Femi Oyewole,Ogbeni Mojoyinoluwa Ayoyemi ati Ogbeni Tijani Adegbola .Koko ipade won da le ona lati mu ise iroyin de ibi giga beeni won tun soro lori ona ti awon araalu yoo fi mo riri ise iroyin lawujo.


No comments:
Post a Comment