Ide n ja,awon ogun ojo pipe n se wole bee ni opo eeyan ti n ri isegun si oniruuru ogun aye won.Ojo kinni titi di ogbon ojo osu karun yii ni isoji agbayanu naa yoo fi waye ti Oluso Oladele Ogundipe Genesis si ti n fi adura se ogun ota wole ninu aye opo eeyan.Oluso Genesis tun ba Baba Adeboye sedaro omo re to darapo mo awon eeyan mimo lose to koja,Pasito Dare Adeboye lo padanu emi re leni odun mejilelogoji laise aisan rara.Oluso Genesis wa n gbadura fun baba Adeboye pe Olorun yoo dawo ibi duro ninu aye awon omoleyin Kristi.


No comments:
Post a Comment