Alaaji Abass Obesere se Waasi Ramadan nilu Eko. - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Lemon Friday

Lemon Friday
Lemon Friday

Monday, May 10, 2021

Alaaji Abass Obesere se Waasi Ramadan nilu Eko.


Ojo satide ose to koja ni gbajumo olorin Fuji nni iyen Alaaji Abass Akande Obesere se Waasi Ramadan nilu Eko.Awon olorin isilaamu bii Alaaji Sidiq ati Alaaja Aminat Obi rere lo wa nibe lojo naa.

Oniwaasi agbaaye nni iyen Sheikh Alfulany lo ye ko se adari eto sugbon ti sunkeere fakeere oko ko je ki baba naa de ibi waasi sugbon won fi owo gidi ranse, oba asakasa gege bii awon ololufe  Obesere se maa n pe e wa fi emi imoore han si gbogbo awon to wa nibe lojo naa. 

No comments:

Post a Comment

Pages