Maa reti ibinu Olorun ti o ba kuna lati toro idariji ese laipe----- Ogbeni Bamgbose gba Oloye Sunday Igboho l'amoran - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Adron Promo

Adron Promo
https://blog.adronhomes.com/promotional/

Wednesday, May 12, 2021

Maa reti ibinu Olorun ti o ba kuna lati toro idariji ese laipe----- Ogbeni Bamgbose gba Oloye Sunday Igboho l'amoran

Okan ninu awon oludari esin lorile ede yii ti so fun Oloye Sunday Igboho pe ko tete toro idariji ese pelu Oro to so si Olori ijo irapada iyen baba Adeboye lasiko to baba naa padanu omo re to n je Dare.Oloye Igboho so pe enikeni ti ko ba fowo si Orile ede Oodua laarin awon agbaagba Yoruba le maa padanu ohunkohun.
Loooto ni Oloye Sunday Igboho ti so pe Oro ti oun so naa ko ri bi awon eeyan ti se n gbe e kiri rara sugbon ti Ogbeni Bamgbose ti so pe yoo dara ki Oloye Igboho tete toro idariji ese fun ohun to so yii.Pasito Dare Adeboye jade laye leni odun mejilelogoji ti won si ti sinku re.


No comments:

Post a Comment

Pages