O ga o !a se ole ni Olajide gbajumo oserekunrin onitiata - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Adron Promo

Adron Promo
https://blog.adronhomes.com/promotional/

Wednesday, May 12, 2021

O ga o !a se ole ni Olajide gbajumo oserekunrin onitiata

Owo awon olopaa ipinle Oyo ti te gbajumo onitiata toruko re n je Olajide Olumide nilu Ibadan,adugbo Eleyele ni iko olopaa ipinle Oyo ti safihan Olajide pelu enikeji re to n je Wemimo Adeyanju pelu esun pe won n ja awon eeyan lole owo nipa gbigba akosile owo latinu akanti banki awon eeyan.


No comments:

Post a Comment

Pages