O mase o!Leyin osu marun ti toko-taya yii segbeyawo ni Moto pa won - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

ILEYA TI DE

ILEYA TI DE
ILEYA TI DE

Saturday, May 8, 2021

O mase o!Leyin osu marun ti toko-taya yii segbeyawo ni Moto pa won

Inu ibanuje ni awon molebi Kingsley wa bayii nipinle Delta pelu bi Moto se pa omo won to n je Kingsley atiyawo re Ajoke danu lojo keji osu yii nilu Delta,a gbo pe won fe soda titi ni oko ayokele kan gba won ti iyen si salo loju ese.Koda pelu oyun osu mesan ni Ajoke gbe soda sorun alakeji


No comments:

Post a Comment

Pages