Genesis so pe irin ajo ti oun lo laarin irin ajo igbesi aye oun je ohun ti Olorun mo nipa e,o so pe opo to wa ninu ide ni won ri itusile ti oun si dupe pe ise iyanu ti owo oun sele.
Oluso Oladele wa n be awon onigbagbo ki won kun fun adura lasiko ti won ba n koju isoro nitori pe ifaseyin maa n mu ogo pupo dani fun onigbagbo to ba fi igbekele re sinu Oluwa.


No comments:
Post a Comment