Oluso Oladele Ogundipe Genesis tun ti gba awon onigbagbo nimoran pe ipadaseyin maa n mu ogo ba eda eeyan to ba ni igbagbo ninu Olorun.
O tun je ko di mimo pe Olorun maa n dan awon eda eeyan wo ni.
O ti wa n be awon onigbagbo pe ki won sunmo eleda won lasiko ipenija,omo Bibi ipinle Ogun naa ti so pe ti eeyan ba n koju isoro eyi ki n se opin aye eda eeyan,nitori Olorun ma n dan eda eeyan wo lopo igba.


No comments:
Post a Comment