Ope o ololufe Atorise fun un ni ebun oko ayokele fun ti ayeye ojo ibi e - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Adron Promo

Adron Promo
https://blog.adronhomes.com/promotional/

Thursday, May 13, 2021

Ope o ololufe Atorise fun un ni ebun oko ayokele fun ti ayeye ojo ibi e

Inu idunnu ati ayo ni gbajumo olorin emi nni iyen Lanre Teriba Atorise wa bayii pelu bii okan ninu awon ololufe e to n je Sunday Soyinka to je alase ileese Shoyinmacs iyen ileese to n ta Moto nikeja nilu Eko se fi ebun oko ayokele Lexus GX460 2020 ta a lore.


No comments:

Post a Comment

Pages