Oseretiata okunrin kan ti soro abuku ranse si Iyabo Ojo - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Lemon Friday

Lemon Friday
Lemon Friday

Thursday, May 13, 2021

Oseretiata okunrin kan ti soro abuku ranse si Iyabo Ojo

Joseph Fajuri to je okan lara awon oseretiata okunrin ti irawo re sese n yo ti ju bombu Oro si Iyabo Ojo pe ohun to dara ni ko fi oju awon okunrin to ti fipa ba a lo han.
Fajuri so pe wahala Iyabo ti po ju lori Oro baba Ijesha ti won so pe o fipa ba omo Princess toun naa je oseretiata lo po.


No comments:

Post a Comment

Pages