Wulebantu gege bi oruko ti awon ololufe e maa n pe e,iyen Eniola Badmus ti pariwo sita pe o ti le ni osu meji ti awon kan ti n fi atejise iku paroko si oun.O so pe eeyan naa n leri pe oun yoo gbemi oun,Eniola wa n be awon ololufe re lati maa fo adura ran oun lowo.
Bio tileje pe omo Bibi ipinle Ogun naa so pe eru ko ba oun nitori oun ti fi oro naa to awon agbofinro leti.

No comments:
Post a Comment