Lori Oro baba Ijesha,oju gbamiti fun awon agba oje onitiata----Funsho Adeolu - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

ILEYA TI DE

ILEYA TI DE
ILEYA TI DE

Monday, June 28, 2021

Lori Oro baba Ijesha,oju gbamiti fun awon agba oje onitiata----Funsho Adeolu

Okan lara oseretiata okunrin to tun gbajumo daadaa iyen Ogbeni Funsho Adeolu ti so pe ohun itiju ni awon agba egbe Tampan kan se pelu bi won se fowo ofin de meji ninu awon omo egbe iyen Iyabo Ojo ati Nkechi Blessing.


No comments:

Post a Comment

Pages