Simenti ni won ji,lowo ba te won - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

ILEYA TI DE

ILEYA TI DE
ILEYA TI DE

Monday, June 28, 2021

Simenti ni won ji,lowo ba te won

Owo awon olopaa ti te awon meta kan toruko won n je Lawal,Lekan ati Ogbeni Kayode ti won tan ise Keke wiwa laayo sugbon to je pe simenti ni won n ji ko kiri ilu Ijebu Awa nipinle Ogun,Dpo olopaa tesan ni Awa Ijebu iyen Ogbeni Joshua fidi isele naa mule pe awon baale Ile meta yii lo ji simenti to le ni oodunrun ji sugbon ti owo ti pada te won.


No comments:

Post a Comment

Pages