
Oloye Sunday Igboho ti so pe onye kan ko le ye iwode Yoruba Nation nilu Eko ati pe iwode yii ki n se ona lati fi fa wahala lese rara,o so pe ki awon ara Eko mase beru,biotile je pe Gomina ipinle Eko Ogbeni Sanwoolu ti so pe ko si aye fun iwode kankan nitori oun ko faramo Orile ede Odua nitoun sugbon ti awon ajo alaabo ati awon olopaa ko to i soro rara lori oro iwode naa.


No comments:
Post a Comment