Egbe Tampan ti kilo fawon oseretiata obinrin meji yii,nitori Oro Baba Ijesha - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

ILEYA TI DE

ILEYA TI DE
ILEYA TI DE

Monday, June 28, 2021

Egbe Tampan ti kilo fawon oseretiata obinrin meji yii,nitori Oro Baba Ijesha

Okan Pataki ninu agba oje tiata lokunrin iyen omooba Jide Kosoko ti kilo fun Iyabo Ojo ati Nkechi Blessing pe ki won dekun lati maa soro ibanilorukoje si awon akeegbe won nidi ise tiata mo.
Bee lo tu so pe ko si osere to koja ibawi ati ifofinde latodo egbe Tampan rara.


No comments:

Post a Comment

Pages