Ko si Oro ife laarin emi ati Seneto Dino Melaye o---Biodun Okeowo - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

ILEYA TI DE

ILEYA TI DE
ILEYA TI DE

Monday, June 28, 2021

Ko si Oro ife laarin emi ati Seneto Dino Melaye o---Biodun Okeowo

Omoborty gege bi awon ololufe e se mo o si,iyen Biodun Okeowo to je gbajumo oseretiata obinrin ti soro soke pe ko si ohun to jo Oro ife laarin oun ati Seneto ana kan lati ipinle Kogi iyen Seneto Dino Melaye ati pe ko si Oro to je mo totomeleto laarin awon.
O je ko di mimo pe oun ko ti i se idi balabala de odo Ogbeni Dino rara ati pe ki awon ololufe oun tako iroyin eleje to n lo lowo nigboro pe oun gan an ni odada to da ija sile laarin osere egbe oun to n je Iyabo Ojo ati Ogbeni Dino.


No comments:

Post a Comment

Pages