Jamiu ati Seun loruko awon gendekunrin ti e n wo foto won yii,omo egbe okunkun ni won ,ose to koja ni owo te won ladugbo Orelope ni Ilogbo Ota ipinle Ogun.
Awon egbe okunkun otooto ni won n ja ti awon gendekunrin yii si wa lara won,awon olopaa ti ko awon mejeeji ti won yoo si foju bale ejo laipe.
Iroyin Tojubọle jẹ iroyin ori ayelujara to n kọ nipa awọn ohun to n lọ lagbegbe wa, yala l'agbo amuludun, iyẹn awọn oṣere; iṣẹlẹ kayeefi; eto oṣelu ati iṣejọba pẹlu oniruuru ẹka iroyin kaakiri agbaye.
No comments:
Post a Comment