Awon aye ti bu iya mi ni Alaso kan ri---- Oluso Oladele Ogundipe Genesis - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

ILEYA TI DE

ILEYA TI DE
ILEYA TI DE

Monday, June 28, 2021

Awon aye ti bu iya mi ni Alaso kan ri---- Oluso Oladele Ogundipe Genesis

Inu Ile ijosin re to wa nliu Eko ni Oluso Oladele Ogundipe eniti gbogbo eeyan mo si Genesis ti gba awon oniroyin lalejo ti iranse Olorun alaaye naa si ti je ko di mimo pe iya ti o ti je oun nile aye yii ki n se kekere rara.
O salaye pe won ti bu iya oun ni alaso kan ri iyen nigbati awon n ta ata nilu Osodi,o so pe nitori oun gan an ko ni aso lo je ki oun darapo mo ijo Alaso funfun ti Olorun si gba fun oun,Oluso wa n be awon omoleyin Jesu naa lati darapo mo eto oselu kaakiri Orile ede yii.


No comments:

Post a Comment

Pages