Pasito Kumuyi so pe Olorun ko se itewogba idamewa awon elese - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

ILEYA TI DE

ILEYA TI DE
ILEYA TI DE

Saturday, June 19, 2021

Pasito Kumuyi so pe Olorun ko se itewogba idamewa awon elese

Loooto ni opo ti n gbe iroyin naa kiri pe Olori ijo Deeper life iyen baba Kumuyi ti so pe oun yoo maa da owo idamewa awon omo ijo oun to je 'elese'pada sugbon ti baba yii ti so pe kii n se ohun ti oun so niyen
Baba Kumuyi so pe Olorun ko niilo owo awon "elese'ni ohun ti oun n so ati pe Olorun ko feran elese rara.


No comments:

Post a Comment

Pages