Awon molebi oloogbe Badru to jona ni soosi ti folopaa gbe iyawo oloogbe - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

ILEYA TI DE

ILEYA TI DE
ILEYA TI DE

Monday, July 5, 2021

Awon molebi oloogbe Badru to jona ni soosi ti folopaa gbe iyawo oloogbe

Won ko tile to ti ikunle abiamo mo arabinrin naa lara pelu bi awon molebi oko re iyen oloogbe Kayode Badru to jona mo soosi ibi to ti n se adura itusile se ti so pe iyawo re mo nipa iku omo won to ku leyin osu die to de lati Orile ede Dubai.


No comments:

Post a Comment

Pages