Awon ololufe Yomi Fabiyi n binu si i,ese to se gan an re e - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

ILEYA TI DE

ILEYA TI DE
ILEYA TI DE

Monday, July 5, 2021

Awon ololufe Yomi Fabiyi n binu si i,ese to se gan an re e

Nise ni opo ninu awon ololufe Yomi Fabiyi n soro buruku si i pelu fiimu Oko Iyabo to sese gbe jade,won ni nitori oro baba Ijesha ni Ogbeni Yomi se gbe fiimu naa jade.Bi awon oseretiata egbe re se n binu si i naa ni awon ololufe fiimu Yoruba n so pe iwa ti Yomi wu naa ku die kaa to.


No comments:

Post a Comment

Pages