Awon oniseese kilo fawon ijoba ipinle Ogun - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

ILEYA TI DE

ILEYA TI DE
ILEYA TI DE

Wednesday, July 14, 2021

Awon oniseese kilo fawon ijoba ipinle Ogun

Gbogbo awon oniseese nipinle Ogun ti pa enu po lati sekilo fawon oludari isejoba nipinle Ogun pe ki won jawo ninu didasi ati yan oba nipinle naa,won so pe ki ijoba ipinle naa mase da si eto yiyan oba sipo kaakiri ipinle naa.


No comments:

Post a Comment

Pages