Aisan eje riru ati ifunpa giga la gbo pe o ran Baale onirele ati oniwa tutu yii lo sorun apapandodo Koda inu sunkeere fa keere oko lati agbegbe Agege si Ikeja lo ti dake,nigba to n lo si osibita LASUTH nikeja ni elemi ti gba a.
Ojo keta ti awon adigunjale pa Ogbeni Afuye ti oun naa je gbajumo sorosoro ni ilu Ondo ni Oloogbe Dapo naa tun ta teru nipa.
Won ti toju oku Baale Dapo si Ile igbokupamosi to wa ni Agbegbe Ikeja.Adura wa ni pe Olorun yoo da awon omo oloogbe si.


No comments:
Post a Comment