Purofeso Lufadeju so pe ijoba apapo ti setan lati mu ona ifetosomo Bibi miiran jade laipe.Dokita Olorunmibe Mamora naa ti be awon oniroyin lati fun ipe naa sita ni kikan pe omo pupo lairi itoju ko dara.
Dokita Christopher Aimakhu to je okan ninu awon dokita ni Ile iwosan UCH ni Ibadan naa so pe opo okunrin ati obinrin ni won feran ibalopo sugbon ti won ko mo ona lati feto somo Bibi.Purofeso Abubakar Panti lati yunifasiti Dan Fodio nipinle Sokoto naa so pe die ninu awon okunrin ni won ko feran lati maa yo kinni won jade lara obinrin lasiko ti won ba fe damira(withdrawal)ti o si so pe ti eyi ba ri bee o di dandan ki awon obinrin maa lo oogun oyinbo lati fi feto somo Bibi.

No comments:
Post a Comment