Aburo Adunni Ade onitiata ku - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

I

Wednesday, July 14, 2021

Aburo Adunni Ade onitiata ku

Inu ibanuje ni okan lara oseretiata obinrin to tun rewa gidi iyen Adunni Ade wa bayii pelu bo se padanu aburo re okunrin leyin aisan ojo pipe.Opo awon osere akeegbe re lo ba a daro lori ero ayelujara


No comments:

Post a Comment

Pages