Ogbeni Ismaila at'ebi re ku sinu Ile won nilu Abeokuta - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

I

Wednesday, July 14, 2021

Ogbeni Ismaila at'ebi re ku sinu Ile won nilu Abeokuta

Ko tii si eni to le so iru iku to pa Ogbeni Ismaila Adeleye ati iyawo re Temitope sinu Ile won ni adugbo Olude ni Abeokuta,Koda omo won naa ba isele naa lo.Ojo akoko ti won sun inu Ile yii la gbo pe oku won ni awon molebi won ba nile.


No comments:

Post a Comment

Pages