Ina s'eyo lasiko asale'abela titan fun idaro oloogbe T B Joshua - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

I

Monday, July 12, 2021

Ina s'eyo lasiko asale'abela titan fun idaro oloogbe T B Joshua

Ale ojo monde ni Ina deede s'eyo lasiko ti awon omo ijo soosi Synagogue n seto asale Ina abela titan fun idaro oludasile ijo won to salaisi laipe yii.
Loooto ni ko si enikeni to darapa nitori awon panapana tete de ibi isele naa to waye ni olu ijo won to wa ni Agbegbe Ikotun nipinle Eko.


No comments:

Post a Comment

Pages