Oko olopaa kolu Keke Marwa nilorin ,eeyan meji lo ku lesekese - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

I

Monday, July 5, 2021

Oko olopaa kolu Keke Marwa nilorin ,eeyan meji lo ku lesekese

Adugbo Sango nilorin nisele naa ti sele nigba ti oko awon olopaa kolu Keke napep,ti eeyan meji si soda sorun alakeji lesekese,awon ero atawon olopaa woya ija leyin isele naa.


No comments:

Post a Comment

Pages