
Gbajumo oseretiata obinrin nni iyen Funke Akindele ti dupe lowo Olorun to tun pa a lerin ayo iyen leyin to segbeyawo pelu Ogbeni Bello ti Olorun si fi ibeji ta won lore,Jenifa so pe igbeyawo oun akoko pelu omo iyaloja Osodi tele iyen Onorebu Almaroof kun fun ibanuje sugbon ti Olorun ti pada pa oun lerin ayo bayii.


No comments:
Post a Comment