Awon Sheik ijo yii lo fori kori lati fi Oye nla yii ta iya naa lore latari awon ise takuntakun ti iya naa ti se ninu ijo Ansar-u-deen,Alaaja Wulemotu je oluferan esin isilaamu ti ko si ko iyan awon elesin isilaamu kere rara.Oba Orin Saheed Osupa lo dalubole lojo naa.


No comments:
Post a Comment