Opo awon ololufe fiimu Yoruba agbelewo ni won ti ju bombu Oro si okan ninu awon oseretiata obinrin nni iyen Dayo Amusa pe omo Bibi ilu Ijebu naa ko si nile oko,ti won si ti n beere igba ti yoo segbeyawo
Dayo ti wa fun won lesi Oro won pe, enikeni ti ko ba mo ojo iku e ko gbodo beere ojo ti oun yoo lo si Ile oko rara.

No comments:
Post a Comment