Ojan ninu awon sorosoro nilu Abeokuta lo pe die ninu awon olorin lati wa gba boolu ,ki won si tun korin ,ti o si je pe Omorapala ati baba Oko ni won pe papo lati wa gba boolu,ti Obesere si ri bodi ti e gbe ju ti Sefiu lo.
Gbogbo awon to wa nibe lojo naa ni won n so pe Obaadan gege bii inagije Obesere mo boolu gba ju Sefiu lo.


No comments:
Post a Comment