Oseretiata obinrin Nkechi Blessing daku lojo isinku mama e - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

ILEYA TI DE

ILEYA TI DE
ILEYA TI DE

Sunday, October 17, 2021

Oseretiata obinrin Nkechi Blessing daku lojo isinku mama e

Agbegbe Ojodu nilu Eko ni eto ayeye oku mama aeewa oseretiata obinrin nni iyen Nkechi Blessing ti waye,ojo satide to koja yii ni ayeye naa waye,a gbo pe iku iya Nkechi iyen iya Gloria Sunday dun awon omo e paapaa julo Nkechi,to si mu u daku lo lojo isinku naa.


No comments:

Post a Comment

Pages