Ose to koja ni awon ololufe Oganla ,iyen awon ololufe Orin Fuji gbe foto hoteeli nla kan sori ero ayelujara pe Olori ebi Oganla iyen Wasiu Alabi Pasuma ti ko Oteeli awosifila kan si igboro ilu Eko,sugbon ti asiri ti pada tu pe Pasuma ko lo ni oteeli naa.
A gbo pe won fe fi Oro oteeli you wu Osupa lori ni,sugbon to je pe gele mawobe ni Olori ebi Olufimo iyen Saheed Osupa we si Oro oteeli ti won ni Pasuma ko lati fi wu u lori

No comments:
Post a Comment