Ojo Monde ose yii ki n se ojo to dara rara paapaa laarin awon sorosoro Ori redio pelu bi iku se wole mu okan ninu won lo lojiji.Sola Otuseso Oyebola to n sise pelu redio ipinle Eko ni iku mu lo leyin ose die to soku iya re tan.
Ile iwosan gbogbonise kan nilu Eko ni emi ti bo lara Oloogbe,ti opo awon sorosoro Ori redio si wa ninu ibanuje titi di bi a se n ko iroyin yii.Adura wa ni pe ki Olorun dawo iku ojiji duro.
Iroyin Tojubọle jẹ iroyin ori ayelujara to n kọ nipa awọn ohun to n lọ lagbegbe wa, yala l'agbo amuludun, iyẹn awọn oṣere; iṣẹlẹ kayeefi; eto oṣelu ati iṣejọba pẹlu oniruuru ẹka iroyin kaakiri agbaye.
No comments:
Post a Comment