Alaaji Abass ti wa be awon ololufe Orin Fuji ki won mase binu pe owo ode ere ti awon n gba lowo won tun ti goboi si i.Alaaji Kudus gege bii inagije re ti wa je ko di mimo pe Orin takasufe ko le bori Orin Fuji laelae,bee lo n be awon ololufe e lati ba a ra Orin re tuntun to n bo lona ti akole re n je 'o ye Olorun.


No comments:
Post a Comment