Odun karun re e ti omo oga onimoto nilu Eko tele iyen Alaaji Adebayo Success to segbeyawo ki Olorun to sese fi ibeji ta a lore lojo tuside ose yii.
Inu idunnu ati Ayo ni pupo ninu awon oseretiata kaakiri wa bayii ,pelu bi okan ninu won iyen Bimbo Success se bi ibeji lojo keji ayeye ojo ibi e
No comments:
Post a Comment