Gongo so lojo ti Wasiu Ayinde S'egbeyawo pelu Emmanuella - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

ILEYA TI DE

ILEYA TI DE
ILEYA TI DE

Friday, November 19, 2021

Gongo so lojo ti Wasiu Ayinde S'egbeyawo pelu Emmanuella

Ilu Abeokuta mi titi lojo toside to koja,Aafin Alake tile Egba ni ayeye naa ti waye,Mayegun Ile Yoruba iyen Alaaji Wasiu Ayinde lo gbe iyawo tuntun,awon oba Alade atawon eeyan Pataki lawujo lo wa nibe lojo naa.
Sefiu Alao ti oun naa je olorin Fuji wa nikale,idi ti a ko fi ri awon olorin Fuji to ku ni enikeni ko le so,sugbon ka ma enu egan kuro ,ojo naa dun o larinrin,beeni inu oko ati iyawo n dun,adura wa ni pe 'Ade Ori Okin yoo ri ere pupo ninu igbeyawo re tuntun yii.


No comments:

Post a Comment

Pages