Kaosara lo bi Faroq nigba ti Layinka Agbeke Halpha bi Al-Amin, Oluaye tun fe Jemilat ti iyen si bi Faisat,Yewande iyen Wendy naa bimo fun omo Ojusagbola, Isabella loruko omo Yewande,Fathia Opeyemi naa tun je iyawo ninu Ile Wasiu Ayinde,Titi Masha naa tun bimo meta fun Wasiu oruko okan ninu won ni Sawat,Mayegun tun niyawo lati Ile Hausa,Nana Hawau niyen n je,sugbon Emmanuella loruko iyawo Olori fun gbogbo awon onifuji tuntun n je bayii.
Opo awon obinrin lo bimo fun Wasiu,Bisola Badmus to je oseretiata obinrin naa wa lara awon to bimo fun Oluaye.


No comments:
Post a Comment