Awon agba oje ninu fiimu Yoruba lo wa nibi eto isinku naa,awon bi i,Oga Bello, Dele Odule,Mr Latin to je Olori awon Tampan,awon maketa bii Toymax,Cooperate picture ati Alaaji Ayedun iyen Isolak naa wa nibe.
Kamilu Kompo ati Sanyeri ko duro pe titi rara,a gbo pe won wa loko sinima kan Ni,Femi Adebayo pelu Ronke Oshodi Oke,Alagba Rammy Shitta naa wa nibe,Opebe ati Murphy Afolabi naa wa lati fun baba Suwe ni eye ikeyin.
A ko ri opo awon oseere to ti ara baba Suwe dide rara,awon to wa nibe lojo naa n so pe ko Dara bi awon sisi lenu ise fiimu tiata bii,Iyabo Ojo,Fathia Balogun,Toyin Ajeyemi atawon beebee lo ko se si nibe,a ri Fali werepe,Yetunde Wunmi ati Madam Saje,Oyiboyi naa wa nibe,Ogbeni Dele Matti,Kakawa,Alaaji Yinka Quadri naa wa nibe.
No comments:
Post a Comment