Asiri tu!Suwe ko ni iyawo akofe Oloogbe Baba Suwe - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

ILEYA TI DE

ILEYA TI DE
ILEYA TI DE

Saturday, November 27, 2021

Asiri tu!Suwe ko ni iyawo akofe Oloogbe Baba Suwe

Obinrin ti e n wo aworan e yii ni iyawo akoko to Koko bimo fun Oloogbe Babatunde Omidina iyen baba Suwe.Leyin Arabinrin yii ni baba Suwe fe Suwebatu,opo obinrin miiran lo tun bimo fun baba Suwe.


No comments:

Post a Comment

Pages