Gbogbo ojo keji osu kinni ni ayeye ojo ibi gbajumo sorosoro Ori redio nni iyen Oloye Abiodun Adeoye Afefe oro,ti omo Bibi ilu Abeokuta naa si n dupe lowo adeda to da emi re si.
Awon akeegbe re atawon ololufe re lo n ba a dupe,ileese iwe iroyin tojubole naa n ki omo olojo ibi pe'api batide tuuu yuuuuu.Emi yin a s'opo odun l'aye.
Iroyin Tojubọle jẹ iroyin ori ayelujara to n kọ nipa awọn ohun to n lọ lagbegbe wa, yala l'agbo amuludun, iyẹn awọn oṣere; iṣẹlẹ kayeefi; eto oṣelu ati iṣejọba pẹlu oniruuru ẹka iroyin kaakiri agbaye.
No comments:
Post a Comment