Kemi salaye ohun to oju re ri pelu aisan kan to ko lu u,to si mu u ro pe emi oun yoo sonu,Koda o so pe oun ti ko iwe ikosile bi won se maa pin ogun oun ati ibi ti won maa sin oku oun si ki Olorun to doola emi oun.
Gbogbo awon to ri ohun ti okan ninu awon oseretiata obinrin iyen Kemi Afolabi so lori ero ayelujara re l'ose to koja ni won ti n ba obinrin naa dupe lowo Olorun.
No comments:
Post a Comment