A gbo pe ale ojo tuside ni baba naa de lati ilu Abuja,ti olojo si de ni ojo wesidee,ti opo awon ololufe ati awon omo Bibi ilu Ibadan si ti n sedaro re.Ojo keji leyin ti iroyin iku Oloye Sonekan to je Olori Orile ede yii lasiko ijoba fidi he-e gba igboro ni iku tun ti mu Oloye Akala lo .


No comments:
Post a Comment