Ojo Sannde Oni yii gan an ni ojo ibi Oba Bolarinwa Bukola Akerele,oun ni alase ati oludari ileese Source auto,oun naa ni oludasile ileese Akerele farm bee naa lo tun je alase ileese Bola logistic,to si je pe Oni yii gan an lo n sojo ibi.
J'aye Ori e jare baba Modupe,baba Boluwatife,Baba Micheal ,baba Ayomide maa jo sibi to wun e.Ojiji Olodumare akorin oba lo ni ka so fun e pe emi e a sopo odun laye.Api Baide tuu yuuu.
Iroyin Tojubọle jẹ iroyin ori ayelujara to n kọ nipa awọn ohun to n lọ lagbegbe wa, yala l'agbo amuludun, iyẹn awọn oṣere; iṣẹlẹ kayeefi; eto oṣelu ati iṣejọba pẹlu oniruuru ẹka iroyin kaakiri agbaye.
No comments:
Post a Comment