Gbogbo ojo ketadinlogun osu kinni odun ni ojo ibi Oba Bolarinwa Bukola Akerele,oke okun ni baba Modupe fi sebugbe,baba Bolu,baba Ayomide,baba Micheal maa jo sibi to wun e jare.Alase ileese Source auto,oun naa ni oludari ileese Akerele farm ati Bless Bola logistic,Adio olowo Ori Asunke, adura wa ni pe wa a se pupo odun l'aye ninu alaafia, owo ati ifokanbale.
Sunday, January 16, 2022

Oba Akerele lo n s'ojo ibi
Ẹka Iroyin
# Lagbo Amuludun
Pin-in Kaakiri
NIPA IROYIN TOJUBOLE
Lagbo Amuludun
Labels:
Lagbo Amuludun
Subscribe to:
Post Comments (Atom)
Author Details
Iroyin Tojubọle jẹ iroyin ori ayelujara to n kọ nipa awọn ohun to n lọ lagbegbe wa, yala l'agbo amuludun, iyẹn awọn oṣere; iṣẹlẹ kayeefi; eto oṣelu ati iṣejọba pẹlu oniruuru ẹka iroyin kaakiri agbaye.
No comments:
Post a Comment